Native Bible

Psalms 119:66 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kọ́ mi ní ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere, nítorí mo gbàgbọ́ nínú àṣẹ rẹ.

Psalms 119:66 in English

Psalms 119:66 · Berean Standard Bible

Teach me good judgment and knowledge, for I believe in Your commandments.

Context

64Ayé kún fún ìfẹ́ rẹ, Olúwa, kọ́ mi ní òfin rẹ. 65Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ, Olúwa. 66Kọ́ mi ní ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere, nítorí mo gbàgbọ́ nínú àṣẹ rẹ. 67Kí a tó pọ́n mi lójú èmi ti ṣìnà, ṣùgbọ́n ni ìsinsin yìí èmi gbọ́rọ̀ sí ọ̀rọ̀ rẹ. 68Ìwọ dára, ohun tí ìwọ sì ń ṣe rere ni; kọ́ mi ní ìlànà rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.