Saamu 119:64
Psalms 119:64 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ayé kún fún ìfẹ́ rẹ, Olúwa, kọ́ mi ní òfin rẹ.
Psalms 119:64 in English
Psalms 119:64 · Berean Standard Bible
The earth is filled with Your loving devotion, O LORD; teach me Your statutes.
Context
62Ní àárín ọ̀gànjọ́ òru èmi dìde láti fi ọpẹ́ fún ọ
nítorí òfin òdodo rẹ. 63Èmi jẹ́ ọ̀rẹ́ sí gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ,
sí gbogbo àwọn tí ń tẹ̀lé ẹ̀kọ́ rẹ. 64Ayé kún fún ìfẹ́ rẹ, Olúwa,
kọ́ mi ní òfin rẹ. 65Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ
gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ, Olúwa. 66Kọ́ mi ní ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere,
nítorí mo gbàgbọ́ nínú àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.