Native Bible

Psalms 119:56 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí tí mo gba ẹ̀kọ́ rẹ gbọ́.

Psalms 119:56 in English

Psalms 119:56 · Berean Standard Bible

This is my practice, for I obey Your precepts.

Context

54Òfin rẹ ni ọ̀rọ̀ ìpìlẹ̀ orin mi níbikíbi tí èmi ń gbé. 55Ní òru èmi rántí orúkọ rẹ, Olúwa, èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́ 56nítorí tí mo gba ẹ̀kọ́ rẹ gbọ́. 57Ìwọ ni ìpín mi, Olúwa: èmi ti pinnu láti tẹríba sí ọ̀rọ̀ rẹ. 58Èmi ti wá ojú rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: fún mi ní oore-ọ̀fẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìpinnu rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.