Native Bible

Psalms 119:55 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní òru èmi rántí orúkọ rẹ, Olúwa, èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́

Psalms 119:55 in English

Psalms 119:55 · Berean Standard Bible

In the night, O LORD, I remember Your name, that I may keep Your law.

Context

53Ìbínú dì mímú ṣinṣin nítorí àwọn ẹni búburú, tí wọ́n ti kọ òfin rẹ sílẹ̀. 54Òfin rẹ ni ọ̀rọ̀ ìpìlẹ̀ orin mi níbikíbi tí èmi ń gbé. 55Ní òru èmi rántí orúkọ rẹ, Olúwa, èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́ 56nítorí tí mo gba ẹ̀kọ́ rẹ gbọ́. 57Ìwọ ni ìpín mi, Olúwa: èmi ti pinnu láti tẹríba sí ọ̀rọ̀ rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.