Native Bible

Psalms 119:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọ̀nà mi ìbá dúró ṣinṣin láti máa pa òfin rẹ̀ mọ́!

Psalms 119:5 in English

Psalms 119:5 · Berean Standard Bible

Oh, that my ways were committed to keeping Your statutes!

Context

3Wọn kò ṣe ohun tí kò dára; wọ́n rìn ní ọ̀nà rẹ̀. 4Ìwọ ti la ìlànà rẹ̀ sílẹ̀ kí a sì pa wọ́n mọ́ gidigidi. 5Ọ̀nà mi ìbá dúró ṣinṣin láti máa pa òfin rẹ̀ mọ́! 6Nígbà náà, ojú kò ní tì mí nígbà tí mo bá ń kíyèsi àṣẹ rẹ̀ gbogbo. 7Èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú ọkàn ìdúró ṣinṣin bí èmi bá ti kọ́ òfin òdodo rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.