Saamu 119:4
Psalms 119:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ti la ìlànà rẹ̀ sílẹ̀ kí a sì pa wọ́n mọ́ gidigidi.
Psalms 119:4 in English
Psalms 119:4 · Berean Standard Bible
You have ordained Your precepts, that we should keep them diligently.
Context
2Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ń pa òfin rẹ̀ mọ́
tí wọn sì ń wá a pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn. 3Wọn kò ṣe ohun tí kò dára;
wọ́n rìn ní ọ̀nà rẹ̀. 4Ìwọ ti la ìlànà rẹ̀ sílẹ̀
kí a sì pa wọ́n mọ́ gidigidi. 5Ọ̀nà mi ìbá dúró ṣinṣin
láti máa pa òfin rẹ̀ mọ́! 6Nígbà náà, ojú kò ní tì mí
nígbà tí mo bá ń kíyèsi àṣẹ rẹ̀ gbogbo.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.