Saamu 119:164
Psalms 119:164 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yìn ọ́ ní ìgbà méje lójúmọ́ nítorí òfin òdodo rẹ.
Psalms 119:164 in English
Psalms 119:164 · Berean Standard Bible
Seven times a day I praise You for Your righteous judgments.
Context
162Èmi yọ̀ nínú ìpinnu rẹ
bí ẹni tí ó rí ìkógun púpọ̀. 163Èmi kórìíra mo sì kọ èké ṣíṣe
ṣùgbọ́n mo fẹ́ràn òfin rẹ. 164Èmi yìn ọ́ ní ìgbà méje lójúmọ́
nítorí òfin òdodo rẹ. 165Àlàáfíà púpọ̀ wà fún àwọn tí ó ní ìfẹ́ sí òfin rẹ,
kò sì ṣí ohun tí ó lè mú wọn kọsẹ̀. 166Èmi yóò dúró de ìgbàlà rẹ, Olúwa,
èmi yóò sì tẹ̀lé àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.