Native Bible

Psalms 119:163 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi kórìíra mo sì kọ èké ṣíṣe ṣùgbọ́n mo fẹ́ràn òfin rẹ.

Psalms 119:163 in English

Psalms 119:163 · Berean Standard Bible

I hate and abhor falsehood, but Your law I love.

Context

161Àwọn alákòóso ṣe inúnibíni sí mi láìnídìí, ṣùgbọ́n ọkàn mi wárìrì sí ọ̀rọ̀ rẹ. 162Èmi yọ̀ nínú ìpinnu rẹ bí ẹni tí ó rí ìkógun púpọ̀. 163Èmi kórìíra mo sì kọ èké ṣíṣe ṣùgbọ́n mo fẹ́ràn òfin rẹ. 164Èmi yìn ọ́ ní ìgbà méje lójúmọ́ nítorí òfin òdodo rẹ. 165Àlàáfíà púpọ̀ wà fún àwọn tí ó ní ìfẹ́ sí òfin rẹ, kò sì ṣí ohun tí ó lè mú wọn kọsẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.