Saamu 119:110
Psalms 119:110 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ẹni búburú ti dẹ okùn sílẹ̀ fún mi, ṣùgbọ́n èmi kò ṣìnà kúrò nínú ẹ̀kọ́ rẹ.
Psalms 119:110 in English
Psalms 119:110 · Berean Standard Bible
The wicked have set a snare for me, but I have not strayed from Your precepts.
Context
108Olúwa, gba ìyìn àtinúwá ẹnu mi,
kí o sì kọ́ mi ní òfin rẹ̀. 109Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ayé mi wà ni ọwọ́ mi nígbà gbogbo,
èmi kò ní gbàgbé òfin rẹ. 110Àwọn ẹni búburú ti dẹ okùn sílẹ̀ fún mi,
ṣùgbọ́n èmi kò ṣìnà kúrò nínú ẹ̀kọ́ rẹ. 111Òfin rẹ ni ogún mi láéláé;
àwọn ni ayọ̀ ọkàn mi. 112Ọkàn mi ti lé pípa òfin rẹ mọ́
láé dé òpin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.