Saamu 119:112
Psalms 119:112 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọkàn mi ti lé pípa òfin rẹ mọ́ láé dé òpin.
Psalms 119:112 in English
Psalms 119:112 · Berean Standard Bible
I have inclined my heart to perform Your statutes, even to the very end.
Context
110Àwọn ẹni búburú ti dẹ okùn sílẹ̀ fún mi,
ṣùgbọ́n èmi kò ṣìnà kúrò nínú ẹ̀kọ́ rẹ. 111Òfin rẹ ni ogún mi láéláé;
àwọn ni ayọ̀ ọkàn mi. 112Ọkàn mi ti lé pípa òfin rẹ mọ́
láé dé òpin. 113Èmi kórìíra àwọn ọlọ́kàn méjì,
ṣùgbọ́n èmi fẹ́ òfin rẹ. 114Ìwọ ni ààbò mi àti asà mi;
èmi ti mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.