Native Bible

Psalms 118:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa ti ṣe èyí, ó ṣe ìyanu ní ojú wa.

Psalms 118:23 in English

Psalms 118:23 · Berean Standard Bible

This is from the LORD, and it is marvelous in our eyes.*

Context

21Èmi yóò fi ọpẹ́ fún ọ, nítorí ó dá mi lóhùn; ìwọ sì di ìgbàlà mi. 22Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, ni ó di pàtàkì igun ilé; 23Olúwa ti ṣe èyí, ó ṣe ìyanu ní ojú wa. 24Èyí ni ọjọ́ tí Olúwa dá: ẹ jẹ́ kí ayọ̀ kí inú wa sì máa dùn nínú rẹ̀. 25Olúwa, gbà wá; Olúwa, fún wa ní àlàáfíà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.