Native Bible

Psalms 118:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa, gbà wá; Olúwa, fún wa ní àlàáfíà.

Psalms 118:25 in English

Psalms 118:25 · Berean Standard Bible

O LORD, save us, we pray.* We beseech You, O LORD, cause us to prosper!

Context

23Olúwa ti ṣe èyí, ó ṣe ìyanu ní ojú wa. 24Èyí ni ọjọ́ tí Olúwa dá: ẹ jẹ́ kí ayọ̀ kí inú wa sì máa dùn nínú rẹ̀. 25Olúwa, gbà wá; Olúwa, fún wa ní àlàáfíà. 26Ìbùkún ni ẹni tí ń bọ̀ wá ní orúkọ Olúwa. Àwa ti fi ìbùkún fún ọ láti ilé Olúwa wá. 27Olúwa ni Ọlọ́run, ó ti mú ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ tàn sí wa lára pẹ̀lú ẹ̀ka igi ní ọwọ́, ó dára pọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ń wọ́ nínú ayọ̀ ẹ fi okùn di ẹbọ náà mọ́ ìwo pẹpẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.