Native Bible

Psalms 113:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ta ló dàbí Olúwa Ọlọ́run wa, tí ó gbé ní ibi gíga.

Psalms 113:5 in English

Psalms 113:5 · Berean Standard Bible

Who is like the LORD our God, the One enthroned on high?

Context

3Láti ìlà-oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀ orúkọ Olúwa ni kí a máa yìn. 4Olúwa ga lórí gbogbo orílẹ̀-èdè, àti ògo rẹ̀ lórí àwọn ọ̀run. 5Ta ló dàbí Olúwa Ọlọ́run wa, tí ó gbé ní ibi gíga. 6Tí ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ láti wò òun tí ó ń bẹ lọ́run, àti nínú ayé! 7Ó gbé òtòṣì dìde láti inú erùpẹ̀, àti pé ó gbé aláìní sókè láti inú ààtàn wá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.