Saamu 109:7
Psalms 109:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kí a dá a lẹ́bi nígbà tí a bá ṣe ìdájọ́ kí àdúrà rẹ̀ kí ó lè di ìkọ̀sílẹ̀.
Psalms 109:7 in English
Psalms 109:7 · Berean Standard Bible
When he is tried, let him be found guilty, and may his prayer be regarded as sin.
Context
5Wọ́n sì fi ibi san ìre fún mi
àti ìríra fún ìfẹ́ mi. 6Yan àwọn ènìyàn búburú láti dojúkọ
jẹ́ kí àwọn olùfisùn
dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀. 7Kí a dá a lẹ́bi nígbà tí a bá ṣe ìdájọ́
kí àdúrà rẹ̀ kí ó lè di ìkọ̀sílẹ̀. 8Kí ọjọ́ rẹ̀ kí ó kúrú;
kí ẹlòmíràn kí ó rọ́pò iṣẹ́ rẹ̀. 9Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di aláìní baba
kí aya rẹ̀ sì di opó.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.