Native Bible

Psalms 109:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n sì fi ibi san ìre fún mi àti ìríra fún ìfẹ́ mi.

Psalms 109:5 in English

Psalms 109:5 · Berean Standard Bible

They repay me evil for good, and hatred for my love.

Context

3Wọ́n fi ọ̀rọ̀ ìríra yí mi káàkiri; wọ́n bá mi jà láìnídìí 4Nípò ìfẹ́ mi, wọn ń ṣe ọ̀tá mi, ṣùgbọ́n èmi ń gba àdúrà. 5Wọ́n sì fi ibi san ìre fún mi àti ìríra fún ìfẹ́ mi. 6Yan àwọn ènìyàn búburú láti dojúkọ jẹ́ kí àwọn olùfisùn dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀. 7Kí a dá a lẹ́bi nígbà tí a bá ṣe ìdájọ́ kí àdúrà rẹ̀ kí ó lè di ìkọ̀sílẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.