Saamu 106:35
Psalms 106:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣùgbọ́n wọ́n dàpọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, wọ́n sì gbà láti ṣe bí àṣà wọn.
Psalms 106:35 in English
Psalms 106:35 · Berean Standard Bible
but they mingled with the nations and adopted their customs.
Context
33Nítorí tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Ẹ̀mí Ọlọ́run.
Ọ̀rọ̀ àìdára sì ti ẹnu Mose wá. 34Wọn kò pa àwọn ènìyàn run
gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ fún wọn, 35Ṣùgbọ́n wọ́n dàpọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,
wọ́n sì gbà láti ṣe bí àṣà wọn. 36Wọ́n sì sin àwọn òrìṣà wọn
tí ó di ìkẹ́kùn fún wọn. 37Wọ́n fi àwọn ọmọkùnrin wọn rú ẹbọ
àti àwọn ọmọbìnrin fún òrìṣà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.