Native Bible

Psalms 102:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí tí ọjọ́ mi run bí èéfín; egungun mi sì jóná bí ààrò.

Psalms 102:3 in English

Psalms 102:3 · Berean Standard Bible

For my days vanish like smoke, and my bones burn like glowing embers.

Context

1Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa, jẹ́ kí igbe ẹ̀bẹ̀ mi kí ó wá sí ọ̀dọ̀ rẹ. 2Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi ní ọjọ́ tí èmi wà nínú ìpọ́njú. Dẹ etí rẹ sí mi; nígbà tí mo bá pè, dá mi lóhùn kíákíá. 3Nítorí tí ọjọ́ mi run bí èéfín; egungun mi sì jóná bí ààrò. 4Àyà mi lù, ó sì rọ bí i koríko; mo gbàgbé láti jẹ oúnjẹ mi. 5Nítorí ohùn ìkérora mi, egungun mi lẹ̀ mọ́ ẹran-ara mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.