Saamu 102:11
Psalms 102:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́ èmi sì rọ bí koríko.
Psalms 102:11 in English
Psalms 102:11 · Berean Standard Bible
My days are like lengthening shadows, and I wither away like grass.
Context
9Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi sì da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omijé. 10Nítorí ìbínú ríru rẹ, nítorí ìwọ ti gbé mi sókè, ìwọ sì gbé mi ṣánlẹ̀. 11Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́
èmi sì rọ bí koríko. 12Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé;
ìrántí rẹ láti ìran dé ìran. 13Ìwọ ó dìde ìwọ ó sì ṣàánú fún Sioni,
nítorí ìgbà àti ṣe ojúrere sí i;
àkókò náà ti dé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.