Native Bible

Psalms 102:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé; ìrántí rẹ láti ìran dé ìran.

Psalms 102:12 in English

Psalms 102:12 · Berean Standard Bible

But You, O LORD, sit enthroned forever; Your renown endures to all generations.

Context

10Nítorí ìbínú ríru rẹ, nítorí ìwọ ti gbé mi sókè, ìwọ sì gbé mi ṣánlẹ̀. 11Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́ èmi sì rọ bí koríko. 12Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé; ìrántí rẹ láti ìran dé ìran. 13Ìwọ ó dìde ìwọ ó sì ṣàánú fún Sioni, nítorí ìgbà àti ṣe ojúrere sí i; àkókò náà ti dé. 14Nítorí tí àwọn òkúta jẹ́ inú dídùn sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ; wọ́n sì káàánú erùpẹ̀ rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.