Native Bible

Proverbs 5:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mu omi láti inú kànga tìrẹ, omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ.

Proverbs 5:15 in English

Proverbs 5:15 · Berean Standard Bible

Drink water from your own cistern, and running water from your own well.

Context

13N kò gbọ́rọ̀ sí àwọn olùkọ́ mi lẹ́nu, tàbí kí n fetí sí àwọn tí ń kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́. 14Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá ní àárín gbogbo àwùjọ ènìyàn.” 15Mu omi láti inú kànga tìrẹ, omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ. 16Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà àti odò tí ń sàn lọ sí àárín ọjà? 17Jẹ́ kí wọn jẹ́ tìrẹ nìkan, má ṣe ṣe àjọpín wọn pẹ̀lú àjèjì láéláé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.