Òwe 5:16
Proverbs 5:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà àti odò tí ń sàn lọ sí àárín ọjà?
Proverbs 5:16 in English
Proverbs 5:16 · Berean Standard Bible
Why should your springs flow in the streets, your streams of water in the public squares?
Context
14Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá
ní àárín gbogbo àwùjọ ènìyàn.” 15Mu omi láti inú kànga tìrẹ,
omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ. 16Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà
àti odò tí ń sàn lọ sí àárín ọjà? 17Jẹ́ kí wọn jẹ́ tìrẹ nìkan,
má ṣe ṣe àjọpín wọn pẹ̀lú àjèjì láéláé. 18Jẹ́ kí orísun rẹ kí ó ní ìbùkún;
kí ìwọ ó sì máa yọ nínú aya ìgbà èwe rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.