Òwe 5:14
Proverbs 5:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá ní àárín gbogbo àwùjọ ènìyàn.”
Proverbs 5:14 in English
Proverbs 5:14 · Berean Standard Bible
I am on the brink of utter ruin in the midst of the whole assembly.”
Context
12Ìwọ yóò wí pé, “Mo ti kórìíra ẹ̀kọ́ tó!
Ọkàn mi ṣe wá kórìíra ìbáwí! 13N kò gbọ́rọ̀ sí àwọn olùkọ́ mi lẹ́nu,
tàbí kí n fetí sí àwọn tí ń kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́. 14Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá
ní àárín gbogbo àwùjọ ènìyàn.” 15Mu omi láti inú kànga tìrẹ,
omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ. 16Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà
àti odò tí ń sàn lọ sí àárín ọjà?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.