Native Bible

Proverbs 27:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Òkúta wúwo, erùpẹ̀ sì wúwo ṣùgbọ́n ìbínú aṣiwèrè wúwo ju méjèèjì lọ.

Proverbs 27:3 in English

Proverbs 27:3 · Berean Standard Bible

A stone is heavy and sand is a burden, but aggravation from a fool outweighs them both.

Context

1Má ṣe yangàn nítorí ọ̀la nítorí o kò mọ ohun tí ọjọ́ kan le è mú wáyé. 2Jẹ́ kí ẹlòmíràn yìn ọ́ dípò ẹnu ara rẹ, àní àlejò, kí ó má sì ṣe ètè ìwọ fúnra rẹ̀. 3Òkúta wúwo, erùpẹ̀ sì wúwo ṣùgbọ́n ìbínú aṣiwèrè wúwo ju méjèèjì lọ. 4Ìbínú ni ìkà, ìrunú sì burú púpọ̀ ṣùgbọ́n ta ni ó le è dúró níwájú owú? 5Ìbániwí gbangba sàn ju ìfẹ́ ìkọ̀kọ̀ lọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.