Native Bible

Proverbs 24:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìdáhùn òtítọ́ dàbí ìfẹnukoni ní ẹnu.

Proverbs 24:26 in English

Proverbs 24:26 · Berean Standard Bible

An honest answer given is like a kiss on the lips.

Context

24Ẹnikẹ́ni tí ó wí fún ẹlẹ́bi pé, “Ìwọ lo jàre,” àwọn ènìyàn yóò ṣẹ́ èpè fún un àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kọ̀ ọ́. 25Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi, ọ̀pọ̀ ìbùkún yóò sì wá sórí wọn. 26Ìdáhùn òtítọ́ dàbí ìfẹnukoni ní ẹnu. 27Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ sì rí i pé oko rẹ ti ṣe dáradára; lẹ́yìn náà kọ́ ilé rẹ. 28Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí, tàbí kí o fi ètè rẹ tannijẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.