Òwe 24:27
Proverbs 24:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ sì rí i pé oko rẹ ti ṣe dáradára; lẹ́yìn náà kọ́ ilé rẹ.
Proverbs 24:27 in English
Proverbs 24:27 · Berean Standard Bible
Complete your outdoor work and prepare your field; after that, you may build your house.
Context
25Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi,
ọ̀pọ̀ ìbùkún yóò sì wá sórí wọn. 26Ìdáhùn òtítọ́
dàbí ìfẹnukoni ní ẹnu. 27Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ
sì rí i pé oko rẹ ti ṣe dáradára;
lẹ́yìn náà kọ́ ilé rẹ. 28Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí,
tàbí kí o fi ètè rẹ tannijẹ. 29Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi;
Èmi yóò san ohun tí ó ṣe fún mi padà fún un.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.