Òwe 20:21
Proverbs 20:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀ kì yóò ní ìbùkún ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín.
Proverbs 20:21 in English
Proverbs 20:21 · Berean Standard Bible
An inheritance gained quickly will not be blessed in the end.
Context
19Olófòófó a máa tú àṣírí
nítorí náà yẹra fún ènìyàn tí ń rojọ́ púpọ̀. 20Bí ènìyàn kan bá ṣépè fún baba tàbí ìyá rẹ̀,
ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ni a ó pa kú nínú òkùnkùn biribiri. 21Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀
kì yóò ní ìbùkún ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín. 22Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.”
Dúró de Olúwa yóò sì gbà ọ́ là. 23Olúwa kórìíra òdínwọ̀n èké.
Òsùwọ̀n ìrẹ́jẹ kò sì tẹ́ ẹ lọ́rùn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.