Òwe 20:2
Proverbs 20:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún; ẹnikẹ́ni tí ó bá mú un bínú ba ayé ara rẹ̀ jẹ́.
Proverbs 20:2 in English
Proverbs 20:2 · Berean Standard Bible
The terror of a king is like the roar of a lion; whoever provokes him forfeits his own life.*
Context
1Ẹlẹ́yà ni ọtí wáìnì, aláriwo sì ní ọtí líle;
ẹnikẹ́ni tí ó bá fi tànjẹ kò gbọ́n. 2Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún;
ẹnikẹ́ni tí ó bá mú un bínú ba ayé ara rẹ̀ jẹ́. 3Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà,
ṣùgbọ́n gbogbo aláìgbọ́n a máa tètè wá ìjà. 4Ọ̀lẹ kì í ṣiṣẹ́ oko nígbà tí ó yẹ,
nítorí náà ní àsìkò ìkórè, yóò wá kò sì ní rì nǹkan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.