Òwe 2:14
Proverbs 2:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú, tí ó ṣe inú dídùn sí àyídáyidà àwọn ènìyàn ibi,
Proverbs 2:14 in English
Proverbs 2:14 · Berean Standard Bible
from those who enjoy doing evil and rejoice in the twistedness of evil,
Context
12Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú,
lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn tí ọrọ̀ ọ wọn jẹ́ àyídáyidà, 13ẹni tí ó kúrò ní ọ̀nà ìdúró ṣinṣin
láti rìn ní ọ̀nà tí ó ṣókùnkùn, 14ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú,
tí ó ṣe inú dídùn sí àyídáyidà àwọn ènìyàn ibi, 15ọ̀nà ẹni tí ó wọ́
tí wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ní ọ̀nà wọn. 16Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin,
àní, lọ́wọ́ obìnrin àjèjì tí ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ tannijẹ,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.