Òwe 2:16
Proverbs 2:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin, àní, lọ́wọ́ obìnrin àjèjì tí ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ tannijẹ,
Proverbs 2:16 in English
Proverbs 2:16 · Berean Standard Bible
It will rescue you from the forbidden woman,* from the stranger * with seductive words
Context
14ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú,
tí ó ṣe inú dídùn sí àyídáyidà àwọn ènìyàn ibi, 15ọ̀nà ẹni tí ó wọ́
tí wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ní ọ̀nà wọn. 16Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin,
àní, lọ́wọ́ obìnrin àjèjì tí ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ tannijẹ, 17ẹni tí ó ti kọ ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀
tí ó sì gbàgbé májẹ̀mú tí ó ti dá níwájú Ọlọ́run rẹ̀. 18Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú
ipa ọ̀nà rẹ̀ sọ́dọ̀ àwọn òkú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.