Òwe 19:4
Proverbs 19:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀; ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ tálákà tún kọ̀ ọ́ sílẹ̀.
Proverbs 19:4 in English
Proverbs 19:4 · Berean Standard Bible
Wealth attracts many friends, but a poor man is deserted by his friend.
Context
2Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀,
tàbí kí ènìyàn kánjú kí ó sì ṣìnà. 3Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;
síbẹ̀ ọkàn rẹ̀ yóò máa bínú sí Olúwa. 4Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀;
ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ tálákà tún kọ̀ ọ́ sílẹ̀. 5Ajẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,
ẹni tí ó sì ń tú irọ́ jáde kò ní lọ lọ́fẹ̀ẹ́. 6Ọ̀pọ̀ ń wá ojúrere olórí;
gbogbo ènìyàn sì ni ọ̀rẹ́ ẹni tí ó lawọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.