Òwe 15:18
Proverbs 15:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ènìyàn onínú ríru dá ìjà sílẹ̀ ṣùgbọ́n onísùúrù paná ìjà.
Proverbs 15:18 in English
Proverbs 15:18 · Berean Standard Bible
A hot-tempered man stirs up strife, but he who is slow to anger calms dispute.
Context
16Ó sàn kí ó má pọ̀, kí ìbẹ̀rù Olúwa sì wà
ju ọrọ̀ púpọ̀ pẹ̀lú ìyọnu. 17Oúnjẹ ewébẹ̀ níbi tí ìfẹ́ wà
sàn ju àbọ́pa màlúù tòun ti ìríra. 18Ènìyàn onínú ríru dá ìjà sílẹ̀
ṣùgbọ́n onísùúrù paná ìjà. 19Ọ̀nà ọ̀lẹ ni ẹ̀gún dí,
ṣùgbọ́n ọ̀nà olódodo já geerege ni. 20Ọlọ́gbọ́n ọmọ mú inú baba rẹ̀ dùn,
ṣùgbọ́n aṣiwèrè ènìyàn kẹ́gàn ìyá rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.