Òwe 14:10
Proverbs 14:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọkàn kọ̀ọ̀kan ló mọ ẹ̀dùn ọkàn tirẹ̀ kò sì ṣí ẹnìkan tó le è bá ọkàn mìíràn pín ayọ̀ rẹ̀.
Proverbs 14:10 in English
Proverbs 14:10 · Berean Standard Bible
The heart knows its own bitterness, and no stranger shares in its joy.
Context
8Ọgbọ́n olóye ni láti ronú jinlẹ̀ nípa ọ̀nà wọn
ṣùgbọ́n ìwà òmùgọ̀ aṣiwèrè ni ìtànjẹ. 9Aláìgbọ́n ń dẹ́ṣẹ̀ nígbà tí ó yẹ kí ó ṣe àtúnṣe ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀
ṣùgbọ́n láàrín àwọn olódodo ni a ti rí ojúrere. 10Ọkàn kọ̀ọ̀kan ló mọ ẹ̀dùn ọkàn tirẹ̀
kò sì ṣí ẹnìkan tó le è bá ọkàn mìíràn pín ayọ̀ rẹ̀. 11A ó pa ilé ènìyàn búburú run,
ṣùgbọ́n àgọ́ olódodo yóò máa gbèrú sí i. 12Ọ̀nà kan wà tí ó dàbí i pé ó dára lójú ènìyàn,
ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, a máa jásí ikú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.