Native Bible

Philemon 1:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi.

Philemon 1:24 in English

Philemon 1:24 · Berean Standard Bible

as do Mark, Aristarchus, Demas, and Luke, my fellow workers.

Context

22Ó ku ohun kan, ṣe ìtọ́jú iyàrá àlejò rẹ sílẹ̀ fún mi, nítorí mo ní ìgbàgbọ́ pé a óò tú mi sílẹ̀ fún yín ní ìdáhùn sí àdúrà yín. 23Epafira, òǹdè ẹlẹgbẹ́ mi nínú Kristi Jesu kí ọ. 24Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi. 25Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.