Native Bible

Philemon 1:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín.

Philemon 1:25 in English

Philemon 1:25 · Berean Standard Bible

The grace of the Lord Jesus Christ be with your spirit.*

Context

23Epafira, òǹdè ẹlẹgbẹ́ mi nínú Kristi Jesu kí ọ. 24Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi. 25Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.