Native Bible

Numbers 33:40 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ará Kenaani, ọba Aradi, tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń bọ̀.

Numbers 33:40 in English

Numbers 33:40 · Berean Standard Bible

Now the Canaanite king of Arad, who lived in the Negev in the land of Canaan, heard that the Israelites were coming.

Context

38Nípa àṣẹ Olúwa, Aaroni àlùfáà gùn orí òkè Hori, níbẹ̀ ni ó kú. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù karùn-ún, ọdún ogójì, lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Israẹli ti ilẹ̀ Ejibiti jáde wá. 39Aaroni jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún ó lé mẹ́ta (123) ní ìgbà tí ó kú sí orí òkè Hori. 40Àwọn ará Kenaani, ọba Aradi, tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń bọ̀. 41Wọ́n kúrò ní orí òkè Hori, wọ́n sì pàgọ́ ní Salmona. 42Wọ́n kúrò ní Salmona wọ́n sì pàgọ́ ní Punoni.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.