Numeri 33:42
Numbers 33:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n kúrò ní Salmona wọ́n sì pàgọ́ ní Punoni.
Numbers 33:42 in English
Numbers 33:42 · Berean Standard Bible
They set out from Zalmonah and camped at Punon.
Context
40Àwọn ará Kenaani, ọba Aradi, tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń bọ̀. 41Wọ́n kúrò ní orí òkè Hori, wọ́n sì pàgọ́ ní Salmona. 42Wọ́n kúrò ní Salmona wọ́n sì pàgọ́ ní Punoni. 43Wọ́n kúrò ní Punoni wọ́n sì pàgọ́ ní Obotu. 44Wọ́n kúrò ní Obotu wọ́n sì pàgọ́ ní Iye-Abarimu, ní agbègbè Moabu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.