Native Bible

Numbers 31:46 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ènìyàn sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́jọ (16,000).

Numbers 31:46 in English

Context

44pẹ̀lú ẹgbàá méjìdínlógún (36,000) màlúù 45tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (30,500). 46Àwọn ènìyàn sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́jọ (16,000). 47Lára ààbọ̀ ti àwọn ọmọ Israẹli, Mose yan ọ̀kan lára àádọ́ta ènìyàn àti ẹranko gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún un. Ó sì fi wọ́n fún àwọn ọmọ Lefi, tí ń ṣe olùtọ́jú àgọ́ Olúwa. 48Pẹ̀lú àwọn olórí tí ó wà lórí ẹgbẹẹgbẹ̀rin ogun náà, àti àwọn balógun ọ̀rọ̀ọ̀rún wá sọ́dọ̀ Mose.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.