Native Bible

Numbers 31:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

pẹ̀lú ẹgbàá méjìdínlógún (36,000) màlúù

Numbers 31:44 in English

Context

42Ààbọ̀ tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Israẹli, tí Mose yà sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ọkùnrin tí ó ja ogun. 43Ààbọ̀ tí ìjọ jẹ́ ẹgbàá méjìdínláàádọ́sàn-án ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (337,500) àgùntàn, 44pẹ̀lú ẹgbàá méjìdínlógún (36,000) màlúù 45tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (30,500). 46Àwọn ènìyàn sì jẹ́ ẹgbàá mẹ́jọ (16,000).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.