Numeri 25:17
Numbers 25:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ka àwọn ará Midiani sí ọ̀tá, kí o sì pa wọ́n,
Numbers 25:17 in English
Numbers 25:17 · Berean Standard Bible
“Attack the Midianites and strike them dead.
Context
15Orúkọ ọmọbìnrin Midiani náà tí a pa ní Kosbi ọmọbìnrin Suri, tí ṣe olóyè àwọn ẹ̀yà kan nínú ìdílé kan ní Midiani. 16Olúwa sì tún sọ fún Mose pé, 17“Ka àwọn ará Midiani sí ọ̀tá, kí o sì pa wọ́n, 18nítorí pé wọ́n ṣe sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀tá nígbà tí wọ́n tàn yín nípa ìṣẹ̀lẹ̀ Peori, àti arábìnrin wọn Kosbi ọmọbìnrin ìjòyè Midiani kan, obìnrin tí a pa nígbà tí àjàkálẹ̀-ààrùn ṣẹlẹ̀ nítorí Peori.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.