Native Bible

Numbers 25:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sì tún sọ fún Mose pé,

Numbers 25:16 in English

Numbers 25:16 · Berean Standard Bible

And the LORD said to Moses,

Context

14Orúkọ ọmọ Israẹli tí a pa pẹ̀lú obìnrin Midiani náà ni Simri, ọmọ Salu, olórí ilé kan nínú àwọn ọmọ Simeoni. 15Orúkọ ọmọbìnrin Midiani náà tí a pa ní Kosbi ọmọbìnrin Suri, tí ṣe olóyè àwọn ẹ̀yà kan nínú ìdílé kan ní Midiani. 16Olúwa sì tún sọ fún Mose pé, 17“Ka àwọn ará Midiani sí ọ̀tá, kí o sì pa wọ́n, 18nítorí pé wọ́n ṣe sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀tá nígbà tí wọ́n tàn yín nípa ìṣẹ̀lẹ̀ Peori, àti arábìnrin wọn Kosbi ọmọbìnrin ìjòyè Midiani kan, obìnrin tí a pa nígbà tí àjàkálẹ̀-ààrùn ṣẹlẹ̀ nítorí Peori.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.