Numeri 21:16
Numbers 21:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ rìn dé Beeri, èyí ni kànga tí Olúwa sọ fún Mose, “Kó àwọn ènìyàn jọ èmi ó sì fún wọn ní omi.”
Numbers 21:16 in English
Numbers 21:16 · Berean Standard Bible
From there they went on to Beer,* the well where the LORD said to Moses, “Gather the people so that I may give them water.”
Context
14Ìdí nìyìí tí ìwé ogun Olúwa se wí pé,
“…Wahebu ní Sufa, Òkun Pupa àti
ní odò Arnoni 15àti ní ìṣàn odò
tí ó darí sí ibùjókòó Ari
tí ó sì fi ara ti ìpínlẹ̀ Moabu.” 16Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ rìn dé Beeri, èyí ni kànga tí Olúwa sọ fún Mose, “Kó àwọn ènìyàn jọ èmi ó sì fún wọn ní omi.” 17Nígbà náà ni Israẹli kọ orin yìí pé,
“Sun jáde, ìwọ kànga!
Ẹ máa kọrin nípa rẹ̀, 18nípa kànga tí àwọn ọmọ-aládé gbẹ́,
nítorí àwọn ọlọ́lá ènìyàn ni ó gbẹ́ ẹ;
tí àwọn ọlọ́lá àwọn ènìyàn sì fi ọ̀pá aládé àti ọ̀pá oyè wọn gbẹ́.”
Nígbà náà wọ́n kúrò láti aginjù lọ sí Mattana,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.