Nehemiah 7:8
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àwọn ọmọ Paroṣi jẹ́ ẹgbàá ó lé méjìléláàádọ́sàn-án (2,172)
Nehemiah 7:8 in English
Nehemiah 7:8 · Berean Standard Bible
the descendants of Parosh, 2,172;
Context
6Èyí ni àwọn ènìyàn agbègbè náà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá láti ìgbèkùn, àwọn tí Nebukadnessari ọba Babeli ti kó ní ìgbèkùn (wọ́n padà sí Jerusalẹmu àti Juda, olúkúlùkù sí ìlú u rẹ̀. 7Wọ́n jọ rìn wá pẹ̀lú u Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Asariah, Raamiah, Nahamani, Mordekai, Bilṣani, Misperi, Bigfai, Nehumu, àti Baanah).
Àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn ọkùnrin Israẹli, 8àwọn ọmọ
Paroṣi jẹ́ ẹgbàá ó lé méjìléláàádọ́sàn-án (2,172) 9Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372) 10Arah jẹ́ ẹgbẹ̀tàléláàádọ́ta ó lé méjì (652)
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.