Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372)

Nehemiah 7:9 in English

Nehemiah 7:9 · Berean Standard Bible

the descendants of Shephatiah, 372;

Context

7Wọ́n jọ rìn wá pẹ̀lú u Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Asariah, Raamiah, Nahamani, Mordekai, Bilṣani, Misperi, Bigfai, Nehumu, àti Baanah). Àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn ọkùnrin Israẹli, 8àwọn ọmọ Paroṣi jẹ́ ẹgbàá ó lé méjìléláàádọ́sàn-án (2,172) 9Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372) 10Arah jẹ́ ẹgbẹ̀tàléláàádọ́ta ó lé méjì (652) 11Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìnlá ó lé méjìdínlógún (2,818)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.