Nehemiah 12:9
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bakbukiah àti Unni, àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn dúró sí òdìkejì wọn nínú ìsìn.
Nehemiah 12:9 in English
Nehemiah 12:9 · Berean Standard Bible
Bakbukiah and Unni, their associates, stood across from them in the services.
Context
7Sallu, Amoki, Hilkiah, àti Jedaiah.
Wọ̀nyí ni olórí àwọn àlùfáà àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn ní ìgbà ayé e Jeṣua. 8Àwọn ọmọ Lefi ni Jeṣua, Binnui, Kadmieli, Ṣerebiah, Juda àti Mattaniah ẹni tí òun pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, ni wọn ṣe àkóso orin ìdúpẹ́. 9Bakbukiah àti Unni, àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn dúró sí òdìkejì wọn nínú ìsìn. 10Jeṣua ni baba Joiakimu,
Joiakimu ni baba Eliaṣibu,
Eliaṣibu ni baba Joiada, 11Joiada ni baba Jonatani,
Jonatani sì ni baba Jaddua.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.