Nehemiah 12:11
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Joiada ni baba Jonatani, Jonatani sì ni baba Jaddua.
Nehemiah 12:11 in English
Nehemiah 12:11 · Berean Standard Bible
Joiada was the father of Jonathan,* and Jonathan was the father of Jaddua.
Context
9Bakbukiah àti Unni, àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn dúró sí òdìkejì wọn nínú ìsìn. 10Jeṣua ni baba Joiakimu,
Joiakimu ni baba Eliaṣibu,
Eliaṣibu ni baba Joiada, 11Joiada ni baba Jonatani,
Jonatani sì ni baba Jaddua. 12Ní ìgbé ayé Joiakimu, wọ̀nyí ni àwọn olórí àwọn ìdílé àwọn àlùfáà:
ti ìdílé Seraiah, Meraiah;
ti ìdílé Jeremiah, Hananiah; 13ti ìdílé Esra, Meṣullamu;
ti ìdílé Amariah, Jehohanani;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.