Native Bible

Mark 9:48 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Níbi ti “ ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’

Mark 9:48 in English

Mark 9:48 · Berean Standard Bible

where ‘their worm never dies, and the fire is never quenched.’*

Context

45Bí ẹsẹ̀ rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, gé é sọnù, ó sàn kí ó di akesẹ̀, kí o sì gbé títí ayé àìnípẹ̀kun ju kí o ní ẹsẹ̀ méjì tí ó gbé ọ lọ sí ọ̀run àpáàdì.* 47Bí ojú rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì. 48Níbi ti “ ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’ 49Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò. 50“Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mú un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ní àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.” 9.29 Àwọn àkọsílẹ̀ kan sọ pé, nípa ààwẹ̀ àti àdúrà 9.43 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àjóòkú. 44Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’ 9.45 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àpáàdì. 46Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.