Marku 9:50
Mark 9:50 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mú un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ní àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.” 9.29 Àwọn àkọsílẹ̀ kan sọ pé, nípa ààwẹ̀ àti àdúrà 9.43 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àjóòkú. 44Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’ 9.45 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àpáàdì. 46Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’
Mark 9:50 in English
Mark 9:50 · Berean Standard Bible
Salt is good, but if the salt loses its saltiness, with what will you season it? Have salt among yourselves, and be at peace with one another.”
Context
48Níbi ti
“ ‘kòkòrò wọn kì í kú,
tí iná kì í sì í kú.’ 49Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò. 50“Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mú un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ní àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”
9.29 Àwọn àkọsílẹ̀ kan sọ pé, nípa ààwẹ̀ àti àdúrà
9.43 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àjóòkú. 44Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’
9.45 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí àpáàdì. 46Níbi ti ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.