Mika 5:12
Micah 5:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yóò gé ìwà àjẹ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, ìwọ kì yóò sì ní aláfọ̀ṣẹ mọ́.
Micah 5:12 in English
Micah 5:12 · Berean Standard Bible
I will cut the sorceries from your hand, and you will have no fortune-tellers.
Context
10“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,
“Èmi yóò pa àwọn ẹṣin rẹ̀ run kúrò láàrín rẹ
èmi yóò sì pa àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ run. 11Èmi yóò sì pa ilẹ̀ ìlú ńlá rẹ̀ run,
èmi ó sì fa gbogbo ibi gíga rẹ̀ ya. 12Èmi yóò gé ìwà àjẹ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,
ìwọ kì yóò sì ní aláfọ̀ṣẹ mọ́. 13Èmi yóò pa àwọn ère fínfín rẹ̀ run,
àti ọwọ̀n rẹ̀ kúrò láàrín rẹ̀;
ìwọ kì yóò sì le è foríbalẹ̀
fún iṣẹ́ ọwọ́ rẹ mọ́. 14Èmi yóò fa ère Aṣerah tu kúrò láàrín rẹ̀,
èmi yóò sì pa ìlú ńlá rẹ̀ run.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.