Native Bible

Matthew 5:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn. Ó wí pé,

Matthew 5:2 in English

Matthew 5:2 · Berean Standard Bible

and He began to teach them, saying:

Context

1Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá. 2Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn. Ó wí pé, 3“Alábùkún fún ni àwọn òtòṣì ní ẹ̀mí, nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run. 4Alábùkún fún ni àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀, nítorí a ó tù wọ́n nínú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.