Matiu 5:1
Matthew 5:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá.
Matthew 5:1 in English
Matthew 5:1 · Berean Standard Bible
When Jesus saw the crowds, He went up on the mountain and sat down. His disciples came to Him,
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.